Samuẹli Kinni 14:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá wí fún gbogbo Israẹli pé, “Gbogbo yín, ẹ dúró ní apá kan, èmi ati Jonatani, ọmọ mi, yóo dúró ní apá keji.”Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ṣe ohun tí ó bá tọ́ lójú rẹ.”

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:36-41