Samuẹli Kinni 14:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n wọ inú igbó náà, wọ́n rí i tí oyin ń kán sílẹ̀, ṣugbọn kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè fi ọwọ́ kàn án nítorí pé wọ́n bẹ̀rù ìbúra Saulu.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:17-35