Samuẹli Kinni 14:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ kó ara wọn jọ, wọ́n lọ sójú ogun náà. Wọ́n bá àwọn ọmọ ogun ninu ìdàrúdàpọ̀ níbi tí wọ́n ti ń pa ara wọn.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:11-21