Samuẹli Kinni 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí, baba rẹ̀ pàgọ́ ogun rẹ̀ sí abẹ́ igi pomegiranate kan ní Migironi, nítòsí Gibea. Àwọn ọmọ ogun bíi ẹgbẹta (600) wà ní ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:1-7