Samuẹli Kinni 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Saulu tí wọn ń ṣọ́nà ní Gibea, ní agbègbè Bẹnjamini, rí i tí àwọn ọmọ ogun Filistini ń sá káàkiri.

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:10-20