Samuẹli Kinni 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, wọ́n fi ara wọn han àwọn ará Filistia. Bí àwọn ara Filistia ti rí wọn, wọ́n ní, “Ẹ wò ó! Àwọn Heberu ń jáde bọ̀ wá láti inú ihò òkúta tí wọ́n farapamọ́ sí.”

Samuẹli Kinni 14

Samuẹli Kinni 14:1-14