Samuẹli Kinni 13:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ní ọjọ́ ogun yìí kò sí ẹnikẹ́ni ninu àwọn ọmọ ogun Israẹli tí ó ní idà tabi ọ̀kọ̀ lọ́wọ́, àfi Saulu ati Jonatani ọmọ rẹ̀.

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:12-23