Samuẹli Kinni 13:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli bá fẹ́ pọ́n ohun ìtúlẹ̀ wọn ati ọkọ́ ati àáké ati dòjé, wọ́n níláti lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ará Filistia.

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:10-23