Samuẹli Kinni 13:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹgbẹ́ ọlọ́ṣà, mẹta ninu ọmọ ogun Filistini jáde láti inú àgọ́ wọn, àwọn kan lọ sí apá ọ̀nà Ofira ní agbègbè Ṣuali,

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:9-23