Samuẹli Kinni 13:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli kúrò ní Giligali, ó lọ sí Gibea ní Bẹnjamini. Saulu ka àwọn eniyan tí wọ́n kù lọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n jẹ́ ẹgbẹta (600).

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:10-19