Samuẹli Kinni 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá rò ó wí pé, àwọn ará Filistia tí ń bọ̀ wá gbógun tì mí ní Giligali níhìn-ín, n kò sì tíì wá ojurere OLUWA. Ni mo bá rú ẹbọ sísun.”

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:7-14