Samuẹli Kinni 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti parí rírú ẹbọ sísun náà tán ni Samuẹli dé. Saulu lọ pàdé rẹ̀, ó sì kí i káàbọ̀.

Samuẹli Kinni 13

Samuẹli Kinni 13:1-13