Samuẹli Kinni 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli tún sọ fún wọn pé, “OLUWA tí ó yan Mose ati Aaroni, tí ó kó àwọn baba ńlá yín jáde wá láti ilẹ̀ Ijipti ni ẹlẹ́rìí.

Samuẹli Kinni 12

Samuẹli Kinni 12:1-14