Samuẹli Kinni 12:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní tèmi, n kò ní ṣẹ̀, nípa aigbadura sí OLUWA fun yín. N óo sì máa kọ yín ní ohun tí ó dára láti máa ṣe ati ọ̀nà tí ó tọ́ fun yín láti máa rìn.

Samuẹli Kinni 12

Samuẹli Kinni 12:16-25