Samuẹli Kinni 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ kò bá gbọ́ ti OLUWA Ọlọrun yín, tí ẹ kò sì pa òfin rẹ̀ mọ́, yóo dojú ìjà kọ ẹ̀yin ati ọba yín.

Samuẹli Kinni 12

Samuẹli Kinni 12:9-21