Samuẹli Kinni 11:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wí fún Nahaṣi pé, “Lọ́la ni a óo jọ̀wọ́ ara wa fún ọ, ohunkohun tí ó bá sì wù ọ́ ni o lè fi wá ṣe.”

Samuẹli Kinni 11

Samuẹli Kinni 11:2-15