Samuẹli Kinni 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nahaṣi, ọba Amoni, kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀, wọ́n lọ gbógun ti ìlú Jabeṣi Gileadi. Àwọn ará Jabeṣi bá sọ fún Nahaṣi pé, “Jẹ́ kí á jọ dá majẹmu, a óo sì máa sìn ọ́.”

Samuẹli Kinni 11

Samuẹli Kinni 11:1-6