Samuẹli Kinni 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Yíyí tí Saulu yipada kúrò lọ́dọ̀ Samuẹli, Ọlọrun sọ ọ́ di ẹ̀dá titun. Gbogbo àwọn àmì tí Samuẹli sọ fún un patapata ni ó sì ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ náà.

Samuẹli Kinni 10

Samuẹli Kinni 10:6-19