Samuẹli Kinni 10:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún wọn pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli ní, ‘Mo kó yín jáde wá láti Ijipti, mo gbà yín kalẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti, ati gbogbo àwọn eniyan yòókù tí wọn ń ni yín lára.’

Samuẹli Kinni 10

Samuẹli Kinni 10:8-20