Samuẹli Kinni 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdọọdún tí wọ́n bá ti lọ sí ilé OLUWA ni Penina máa ń mú Hana bínú tóbẹ́ẹ̀ tí Hana fi máa ń sọkún, tí kò sì ní jẹun.

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:4-13