Samuẹli Kinni 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdọọdún ni Elikana máa ń ti Ramataimu-sofimu lọ sí Ṣilo láti lọ sin OLUWA àwọn ọmọ ogun, ati láti rúbọ sí i. Hofini ati Finehasi, àwọn ọmọ Eli, ni alufaa OLUWA níbẹ̀.

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:1-13