Samuẹli Kinni 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Hana kò bá wọn lọ. Ó wí fún ọkọ rẹ̀ pé, “Bí mo bá ti gba ọmú lẹ́nu ọmọ yìí ni n óo mú un lọ sí ilé OLUWA, níbẹ̀ ni yóo sì máa gbé títí ọjọ́ ayé rẹ̀.”

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:15-28