Samuẹli Kinni 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Hana lóyún, ó bí ọmọkunrin kan, ó sọ ọmọ náà ní Samuẹli, ó ní, “Títọrọ ni mo tọrọ rẹ̀ lọ́wọ́ OLUWA.”

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:12-24