Samuẹli Keji 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Siria dé láti Damasku tí wọ́n ran Hadadeseri, ọba Soba lọ́wọ́, Dafidi pa ẹgbaa mọkanla (22,000) ninu àwọn ọmọ ogun wọn.

Samuẹli Keji 8

Samuẹli Keji 8:1-8