Samuẹli Keji 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹnaya, ọmọ Jehoiada ni olórí àwọn Kereti ati àwọn Peleti (tí ń ṣọ́ ààfin), àwọn ọmọ Dafidi ọkunrin ni wọ́n sì jẹ́ alufaa.

Samuẹli Keji 8

Samuẹli Keji 8:15-18