Samuẹli Keji 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ọba ya àwọn ẹ̀bùn náà sí mímọ́ fún ìlò ninu ilé OLUWA, pẹlu gbogbo fadaka ati wúrà tí ó rí kó láti gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó ti ṣẹgun;

Samuẹli Keji 8

Samuẹli Keji 8:10-18