Samuẹli Keji 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, sọ fún Dafidi iranṣẹ mi pé, ‘Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo mú un kúrò níbi tí ó ti ń ṣọ́ àwọn aguntan, ninu pápá, mo sì fi jọba Israẹli, àwọn eniyan mi.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:1-9