Samuẹli Keji 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ìgbà tí mo ti gba àwọn ọmọ Israẹli kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti títí di àkókò yìí, n kò fi ìgbà kan gbé inú ilé rí, inú àgọ́ ni mò ń gbé káàkiri.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:2-11