Samuẹli Keji 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Natani dá a lóhùn pé, “Ṣe ohunkohun tí ó bá wà ní ọkàn rẹ, nítorí pé OLUWA wà pẹlu rẹ.”

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:2-9