Samuẹli Keji 7:28 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ǹjẹ́ nisinsinyii, OLUWA Ọlọrun, ìwọ nìkan ni Ọlọ́run, òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ, o sì ti ṣèlérí ohun rere yìí fún iranṣẹ rẹ.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:25-29