Samuẹli Keji 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ìlérí ati ìfẹ́ ọkàn rẹ ni o fi ṣe gbogbo nǹkan ńlá wọnyi, kí iranṣẹ rẹ lè mọ̀ nípa wọn.

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:15-29