Samuẹli Keji 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ọba bá wọlé, ó jókòó níwájú OLUWA, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí gbadura pé, “Ìwọ OLUWA Ọlọrun! Kí ni mo jẹ́, kí ni ilé mi jámọ́ tí o fi gbé mi dé ipò yìí?

Samuẹli Keji 7

Samuẹli Keji 7:12-20