Samuẹli Keji 6:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn tí wọ́n ru àpótí ẹ̀rí náà ti gbé ìṣísẹ̀ mẹfa, Dafidi dá wọn dúró, ó sì fi akọ mààlúù kan ati ọmọ mààlúù àbọ́pa kan rúbọ sí OLUWA.

Samuẹli Keji 6

Samuẹli Keji 6:11-14