Samuẹli Keji 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn rẹ̀ bá yipada, ó pinnu pé òun kò ní gbé e lọ sí Jerusalẹmu, ìlú Dafidi mọ́. Dípò bẹ́ẹ̀, ó gbé e lọ sí ilé Obedi Edomu, ará ìlú Gati.

Samuẹli Keji 6

Samuẹli Keji 6:5-11