Samuẹli Keji 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Dafidi jagun gba Sioni, ìlú olódi wọn. Sioni sì di ibi tí wọn ń pè ní ìlú Dafidi.

Samuẹli Keji 5

Samuẹli Keji 5:5-8