Samuẹli Keji 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbi tí àwọn ará Filistia ti ń sá lọ, wọ́n gbàgbé àwọn oriṣa wọn sílẹ̀, Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ sì kó wọn lọ.

Samuẹli Keji 5

Samuẹli Keji 5:18-25