Samuẹli Keji 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Filistia gbọ́ pé wọ́n ti fi Dafidi jọba Israẹli, gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn jáde lọ láti mú un, ṣugbọn Dafidi gbọ́ pé wọ́n ń bọ̀ wá mú òun, ó bá lọ sí ibi ààbò.

Samuẹli Keji 5

Samuẹli Keji 5:15-25