Samuẹli Keji 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi kúrò ní Heburoni lọ sí Jerusalẹmu, ó fẹ́ àwọn obinrin mìíràn kún àwọn aya rẹ̀. Ó sì ní ọpọlọpọ ọmọ sí i, lọkunrin ati lobinrin.

Samuẹli Keji 5

Samuẹli Keji 5:12-21