Samuẹli Keji 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbára Dafidi bẹ̀rẹ̀ sí pọ̀ sí i, nítorí pé OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun wà pẹlu rẹ̀.

Samuẹli Keji 5

Samuẹli Keji 5:7-15