Samuẹli Keji 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Iṣiboṣẹti ọmọ Saulu gbọ́ pé wọ́n ti pa Abineri ní Heburoni, ẹ̀rù bà á gidigidi, ìdààmú sì bá gbogbo àwọn ọmọ Israẹli.

Samuẹli Keji 4

Samuẹli Keji 4:1-5