Samuẹli Keji 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Ọlọrun lù mí pa, bí n kò bá ṣe gbogbo ohun tí ó wà ní ìkáwọ́ mi, láti mú ìlérí tí OLUWA ṣe fún Dafidi ṣẹ,

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:1-16