Samuẹli Keji 3:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò dì ọ́ lọ́wọ́,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò dì ọ́ lẹ́sẹ̀;o ṣubú bí ìgbà tí eniyan ṣubú níwájú ìkà.”Gbogbo eniyan sì tún bú sẹ́kún.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:32-39