Samuẹli Keji 3:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Joabu ati Abiṣai, arakunrin rẹ̀, ṣe pa Abineri tí wọ́n sì gbẹ̀san ikú Asaheli, arakunrin wọn, tí Abineri pa lójú ogun Gibeoni.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:27-34