Samuẹli Keji 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Abineri dé ọ̀dọ̀ Dafidi ní Heburoni pẹlu ogún ọkunrin tí ń bá a lọ, Dafidi se àsè ńlá fún wọn.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:10-28