Samuẹli Keji 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Abineri tọ àwọn àgbààgbà Israẹli lọ, ó ní, “Ó pẹ́ tí ẹ ti fẹ́ kí Dafidi jẹ́ ọba yín.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:10-22