Samuẹli Keji 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá rán àwọn oníṣẹ́ kan sí Iṣiboṣẹti, ọmọ Saulu, pé kí ó dá Mikali, aya òun, tí òun san ọgọrun-un awọ orí adọ̀dọ́ àwọn ará Filistia lé lórí pada fún òun.

Samuẹli Keji 3

Samuẹli Keji 3:7-24