Samuẹli Keji 24:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Oṣù mẹsan-an ati ogúnjọ́ ni ó gbà wọ́n láti lọ káàkiri gbogbo ilẹ̀ Israẹli, lẹ́yìn náà, wọ́n pada sí Jerusalẹmu.

Samuẹli Keji 24

Samuẹli Keji 24:5-16