Samuẹli Keji 24:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àṣẹ tí ọba pa ni ó borí. Ni Joabu ati àwọn ọ̀gágun rẹ̀ bá jáde kúrò níwájú ọba, wọ́n bá lọ ka àwọn ọmọ Israẹli.

Samuẹli Keji 24

Samuẹli Keji 24:1-9