Samuẹli Keji 24:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ pẹpẹ kan sibẹ fún OLUWA, ó sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia. OLUWA gbọ́ adura rẹ̀ lórí ilẹ̀ náà, àjàkálẹ̀ àrùn náà sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ Israẹli.

Samuẹli Keji 24

Samuẹli Keji 24:19-25