Samuẹli Keji 23:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun Israẹli ti sọ̀rọ̀,Àpáta Israẹli ti wí fún mi pé,‘Ẹni yòówù tí ó bá fi òtítọ́ jọba,tí ó ṣe àkóso pẹlu ìbẹ̀rù Ọlọrun,

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:2-8